Full width home advertisement

Cool Worship

Gospel Rap

Post Page Advertisement [Top]

Gbenga Akinfenwa - Aanu Ni Mori Gba
Gbenga Akinfenwa - Aanu Ni Mori Gba cover pix


Song Lyrics
Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh.. /2x

Call: ki ma ma ise tori mo dara, tabi tori mo mo aduraa gba
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh
Call: ki ma ma ise ile ti mo wa o, tabi tori gbogbo iwe ti mo ka eh
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh
Call: Ki ma ma ise tori moni baba Isale, lo mu kokan mi fi bale.
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh

Call: Bi mo ba se njade nile
Aanu!
Call: Bi mo se nkore dele
Aanu!
Call: Mo nsori ire sere
Aanu…ko ma tele mi o

Call: Bi mo nse kole mole o
Response: Aanu!
Call: Bi mo nse kore wole o
Response: Aanu!
Call: Mo nsori ire sere o
Response: Aanu…ko ma tele mi o
Call: ki ma ma ise tori mo dara, tabi tori mo mo aduraa gba
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh
Call: ki ma ma ise ile ti mo wa o, tabi tori gbogbo iwe ti mo ka eh
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh
Call: Ki ma ma ise tori moni baba Isale, lo mu kokan mi fi bale.
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh

Call: Bi mo ba se njade nile o
Aanu!
Call: Bi mo se nkore wole o
Aanu!
Call: Emi ko nsori ire sere
Aanu…ko ma tele mi o

Call: Bi mo ba se nse kole mole o
Response: Aanu!
Call: Bi mo se n testify
Response: Aanu!
Call: Aanu to da owo idajo duro
Response: Aanu…ko ma tele mi o

Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh.. /5x


WATCH VIDEO

2 comments:

  1. I love this song so much that I am tired of listening to, more grace Sir

    ReplyDelete
  2. Beautiful song! More grace sir Gbenga #Anu ni mo rigba

    ReplyDelete

Multiplex Google Ads

Bottom Ad [Post Page]